WON TI TI ILEESE ILERA OKOO PA NILU EKO LORI ESUN AITELE OFIN TO YE

Written by on September 25, 2019

Ijoba Ipinle Eko ti fi agadagodo ti Ileese Ilera Okoo pa ninu Osu Kejo Odun lori esun aitele ofin bo tito ati bo tiye.

Ijoba Ipinle Eko labe Ajo Helath Faculty Monitoring and accreditation  agency, HEFAMAA tenumo pe ojoba Ipinle Eko to setan lati ridaju pe ko soro mo fawon ti ko se onisegun oyinbo, ti won nsise leka ipese ilara.

Akowe agba ajo HEFAMAA, Dr. Abiola Idowu to soro naa leyin abewo won sawon osise ilera pe ijoba nla kaka lati pese ayika to rorun fun ilera to jure faraalu.

Dr. Idowu sofikun pe ajo naa ti fenuko lati maa sode awon osise ilera loore koore nipinle Eko lojuna ati sawari awon koloransi eda laarin won pelu riro araalu lati towonleyin safomo awon kanda inu iresi lka ipese ilera.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background