KOTO IDAMINU MAA SAN NI GEERE

Written by on October 10, 2019

Ipinle Ipinle Eko sope oun nsapa lati jeki gbogbo koto idominu to wa nilu Eko maa san ni geere.

Komisona Eto ayika alamojuto ori omi, Ogbeni Tunji Bello ro awon Olugbe lati mase beru latari ogbara to wopo lawon adugbo kan nilu Eko.

Ogbeni Bello woye pe ijoba ipinle Eko ti ko opo osise sita lati lo maa ko awon koto idaminu to ba ti dipa, leyinti won ti saaju ran awon amoju ero sigboro lati lo wo bilu se wa nipa isele omiyale, kijoba le mo igbese to ye.

O wa rawo ebe saraalu lati dekun dida idoti sinu gota.

Bakana ni ogbeni Bello tun sekilo fawon to kole di ojuna ogbara lati lo pale won mo kawon agbofinro too de wa sise owo won.  


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background