KOKO INU IWE IROYIN FUN OJORU OJO KETA OSU KEWA EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: TEMITOPE OYEFOLU

Written by on October 2, 2019

  • Ijoba Ipinle Eko beere iwadi nipa aisan to kolu awon akeko Ile-ewe Queens College
  • Omiyale se ose ni Ekiti, eyan kan lo ku
  • Ileese Aare so iroyin pe Aare Buhari nlepa lati se ijoba ni gba iketa
  • Ile Nigeria yoo bo lowo ipenija gbogbo, Aare Buhari soro na layajo ominira ile Nigeria.
  • Ile Nijiria je gbese to le ni aadorun Bilionu Dollar, ko si lapa rere, Peter Obi lo so bee.
  • Latari ayeye ayajo ominira, Gomina Ipinle Kogi Yahaya Bello da elewon mokanlelogbon sile.
  • A gbodo di ara wa mu bi osusu owo fun idagbasoke ile Naijiria, Gomina Sanwo-Olu lo so be
  • Ijoba Ile South Africa fun Ileese oko baalu akero Air Peace lanfani lati maa wole-jade sile won lojoojumo.
  • Akeredolu, Sanwo-Olu fe eto ilosiwaju rere
  • A fi odun mokandinlogota sofo pelu opolopo ireti pipe to so opolopo omo Nigeria di alaare-Nyesom Wike.

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background