KOKO INU IWE IROYIN FUN OJORU OJO KEJILELOGUN OSU KINNI ODUN EGBA O-LE-OGUN OLOOTU: TEMITOPE OYEFOLU

Written by on January 22, 2020

  • OWO ELE ORI EPO TIJOBA APAPO NFUN AWON OLOJA EPO SEESE KO TUN LO SOKE LATARI ALEKUN TI WON NBEERE FUN
  • WON FAGILE IPADE AWON GOMINA, ILEESE AARA IFEHONUHAN WAYE NIWO OORUN GUUSU LORI OO AMOTEKUN
  • OWO AGBOFINRO TE DARANDARAN META LORI ESUN FIFI MAALU JE OKO BI OHUN OGBIN JE NI EKITI
  • AWON ALASE GBE IGBIMO ELENI MOKANDINLOGBON KALE LATI YANJU AIGBORANIYE NI IPINLE KWARA ATI SARAKI
  • IBA OREERE LATI ARA EKUTE SEKUPA DOKITA MEJI NI KANO, AWON TO KU NPOSI NI ONDO.
  • ASOFIN MESAN NI IMO DARAPO MO EGBE OSELU APC, PELU BI ILEEGBIMO ASOFIN SE BERE IJOKO PADA
  • AWON OLOKODA ILU EKO KE GBAJARI LORI OFIN MASU MATO LOJUUPOPO
  • OFIN AWON APOOGUN TO TOKA AWON TOJE AYEDERU NINU WON MAA BERE LOSU KERIN
  • OJOGBON WOLE SOYINKAN BU ENU ATE LU BALARABE LORI TITAKO ESO AMOTEKUN

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background