KOKO INU IWE IROYIN FUN OJOISEGUN OJO KERINDINLOGUN OSU KEJE EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: KEHINDE JIMOH

Written by on July 16, 2019

KOKO INU IWE IROYIN FUN OJOISEGUN OJO KERINDINLOGUN OSU KEJE EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019)

OLOOTU: KEHINDE JIMOH

 • Wahala n mile bo, Obasanjo kilo fun Buhari.
 • Ijoba gbodo pese eto abo ni, ki i se kijoba maa ba awon araalu kedun – Oyinlola.
 • Libya ni won ti ko wa lekoo – Awon Ajinigbe.
 • Milionu lona ogbon dollar lawon ajinigbe fe gba lati yonda olori adugbo Buhari.
 • Eto abo to mehe, leta Obasanjo dawa lare – PDP.
 • Agbajowo la fi n soya lori eto abo – Buhari.
 • Yoruba gbodo daabo bo ara won- Fasanmi.
 • Nigeria ko le fara da ikolu eleyemeya mo- Lawan.
 • Ajo awon osise kilo lori alekun owo ina monamona.
 • Eto abo to mehe ti n to – Buhari.
 • Ile igbimo asofin yoo satileyin fun kiko soja wolu lori eto abo – Omo Agege.
 • A o ba egbe APC fa a ni Kogi – Wada.

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background