KOKO INU IWE IROYIN FUN OJOBO OJOKERINDINLOGBON OSU KESAN EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: TEMITOPE OYEFOLU

Written by on September 26, 2019

  • IGBIMO ALASE IJOBA FEC FOWOSI #3,46 FUN ISE AKANSE OJUUPOPO ATI ETO EKO
  • IGBAKEJI AARE OJOGBON YEMI OSINBAJO BERE IJA PELAWON ALALESI ORO
  • MOST REV. HENRY NDUBUKA BO SIPO PRIMATE IJO ANGLICAN FUN SAA ODUN MEWA.
  • AJO ELETO IDIBO SOWOPO PELAJO ISOKAN AGBAYE LORI ILANA ETO IDIBO
  • IPINLE KASTINA GBA OLUKO OTALELEGBERIN ATI MEJE SENU ISE.
  • ILEEJO PASE KIJOBA APAPO GBESE LE ILEETURA KAN TO JE TI OSISE IJOBA NIPINLE KWARA
  • IPINLE EKO SI NILO IYE INA MONAMONA EGBERUN MESAN MEGAWATTS, GOMINA SANWO-OLU LO SO BEE.
  • IPINLE OYO BERE IGBESE LATI GBESELE ILE TI KO BA TI NIWE ASE ONNILE
  • IJOBA IPINLE EKITI SETO LATI FA OJU AWON ONILEESE MORA, KI WON LE DASI ILOSIWAJU ETO EKO
  • OMO EGBE OKUNKUN DANA SUN ILE NIPINLE RIVERS LATARI IKOLU AWON OLOGUN

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background