KOKO INU IWE IROYIN FUN OJOBO OJO KETA OSU KEWA EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: KEHINDE JIMOH

Written by on October 3, 2019

 • Ganduje, Lalong ,Tambuwal jawe olubori.
 • Awon asofin yoo gba Tirilionu meje owo eporobi pada.
 • Ki Buhari mase daa enu iloro pada –PDP
 • E mase gbe igbese lilo eleeketa Aare o –PDP
 • Awon ojogbon Larewa fe ki won fagile ajo JAMB.
 • Awon odo Arewa ro awon omo Nigeria lati mase ka iroyin lori oro to n lo lori igbakeji Aare gbo.
 • Awon egbe osise  taku lori oro owo osu tuntun
 • Awon Igbo ni Kaduna lawon ko ti i gbominira
 • Ihedioha fe ki Eto Abo de lawon ile igbafe
 • Ekiti ni Ipinle ti won pati ju lo—Afe babalola
 • Gomina Makinde tewo gba awon omo oyo mejilelogbon lati ile South -Africa
Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background