KOKO INU IWE IROYIN FUN OJO KERINDINLOGUN OSU KEWA EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU–ABDUL FATAI ABDUL GAFAR

Written by on October 16, 2019

 • AWON AYEDAADE OSISE NLC TIFAGILE IYONSELODI WON WIPE ORO SIN TESIWAJU.
 • WON TIPE IJOBA APAPO LEJO NITORI OWO BILLIONU MEJILELOGOTA NAIRA TI WON RIGBA LOWO IOC.
 • GBESE IJOBA APAPO TI WO TRILLIONU MEJIDINLOGBON NAIRA.
 • AFENIFERE SOPE ITIJU GBA LOJE PE DAURA LON DARI ILEESE ARE LABUJA.
 • FAYEMI RO IJOBA APAPO LATI MAAGBA OWO IBODE NI OPOPONA MAROSE ADO  SILU AKURE.
 • SANWOLU NBERE FUN EYAWO BILLIONU IGBA OLE ADOTA NAIRA LOWO ILEEGBIMO ASOFIN
 • ALAKOSO ETO OGBIN GBOLAHAN LAWAL SOPE OHUN YIO PESE ETO IRORUN FUN AWON AGBE.
 • OBASEKI DI EBI RU OSHIOMOOLE LORI IKOLU TI WON KOLU OHUN.
 • AWON OLUKO BAYELSA FAGILE IYONSE LODI WON.
 • IJOBA IPINLE OSUN ATI OYO TI YONJU ORO ILEEKO LAUTECH.
 • IWE ABA ETO ISUNA ODUN 2020 TI WO IPELE KEJI.
 • ESORA FUN ISOKUSO ORO INEC LOSOBE FUN AWON OLOSELU

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background