KOKO INU IWE IROYIN FUN OJO AJE OJO KERIN OSU KOKANLA EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: TEMITOPE OYEFOLU

Written by on November 4, 2019


 • E YI GOMINA TI KO BA LE SANWO OSU TO KEREJULO FAWON OSISE KURO NIPO, EGBE OSISE NLC LO SO BE
  AWON AFURA MEJI RA OMO MEJI NI EGBERUN LONA OGOJE NAIRA
  ILAJI OWO AGBE YIO MAA FI RA IRINSE WON, MINISITA LO KEDE ORO
 • AARE ILE NAJIRIA, MUHAMMADU BUHARI KE GBAJARE SI BI IWA OMOLUABI SE NRELE LAWON FAASITI WA
 • AWON ADIGUNJALE INU SUNKERE FAKERE WA PADA SENU ISE LAGBEGBE APAPA
 • AJO ESO AGUNBANIRO NYSC SAFIKUN AKOKO ISINU ILU AGUNBANIRO MEJIDINLOGUN FESUN  ASEMASE
 • MILIONU MEWA OWO NAJIRIA LO NGBE PELU AISAN ITO SUGAR, AARE EGBE SAROYE ORO
 • IJOBA IPINLE EDO LO SAGBATERU IKILO, ALAGA APAPO EGBE OSELU APC, ADAMS OSHIOMOLE KE GBAJARI
 • GOMINA IPINLE NASARAWA, ABDULLAHI SILE SELERI LATI PALEMO AWON ATEWOGBORE KURO NIPINLE NKA
 • GOMINA IPINLE EKO, BABAJIDE SANWO-OLU KE SAWON ALASE LEKA ETO IRINNA LATI WONA ABAYO SI ASEMASE AWON AWAKO OKO AFAYAFA
 •  
Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background