IYAWO AWON OLOPA TO WA NI BAREKE MAKINDE NI OSHODI KE GBAJARI E GBAWA SAWON ALASE LATARI BI WON SE FE LEWON KURO

Written by on February 24, 2021

Lara awon iyawo oloopa to nsise ni ago oloopa Makinde ni Bakaki Oshodi ipinle Eko eyiti bareki naa jona, ti opo dukia bana sowo awon omo ganfe nigba fehonuhan Endsars ti seto iwode worowo lati kesijoba ki won ri ti won ro leyin isele laabi naa.

            Awon to bale ise BondFM soro lara won salaye pe pelu bo je pe ministers meji otooto lo ti bewon wo leyin isele naa, sibe ki i tu seni to risi bawon se njenu.

            Won fajuro gidi pe oko won lo to lo sise kookiri ilu Eko nigba tawon omo ganfe tan wi de, ti won si ko opo dukia salo.

            Won sope leyin isele yii, pupo ninu won ni ko ribe gbe mo inu soosi ati mosalasi lawon kan nsun bayii.

            Bi o tite jepe won gbeoriyin fun ijoba apapo atajo ileese olopa fun sisanwo gba mabinu febi awon olopa to padanu emi won , won rawo ebi sijobi lati das si yiyanju isoro awon to padanu dukia.

            Gegebi ogaagba. ileese oloopa ileyi se so, olopa mejidelogun lo be isele naa lo, nigbati awon omo janduku sun ago olopa mefedinlogun ti won si ji opo dukia lo pelu biba opolopo oko awon olopa je.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background