ILEEJO KO TEMILORUN JAWE GBELE E FUN ASOFIN LATINU EGBE OSELU APC NILEEGBIMO ASOFIN IPINLE KWARA

Written by on November 13, 2019

Ileejo kotemilorun to fikale silu Ilorin ti jawe gbele e fun omoileegbimo asofin ipinle Kwara, to nsoju ekun Guusu Ilori labe asia egbe All Progressive Congress, APC Ogbeni Abdul Azeez Oluwawulo, ti won si kede omo egbe oselu Peoples Democratic party, PDP, Ogbeni AbdulRaheem Agboola jejebi eni to jawe olubori lati eyi ekiro naa.

Onidajo Hamman Hwaku to sedajo naa ti wa pase fajo eleto idibo INEC lati pese iwe eri moyege feni tidajo naa gbeleyin.

Igbejo naa da lori idibo abeleegbe oselu APC to saaju kede Alhaji Suleimon AbdulSalam gegebi oludije egbe naa, ki won too tun paaro oruko re si ti AbdulAzeez Olorunwulo.

Agbenuso ki Ogbeni Agboolaku orire.

Bakana, gomina ipinle Kwara, Alhaji AbdulRaheem ti ba ondije lati egbe PDP sleegbimo asofin ipinle naa ogbeni mJimoh AbdulRaheem Agboola yo fun lileejo kotemilorun se kede re gegebi Olubori, pelu ase ki won sebura fun.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background