ILE IGBIMO ASOFIN LO SEESE KAWON TUN PE GOMINA IPINLE EKO ANA LATI WA YANJU AWON ORO KAN TO SOOKUN

Written by on October 11, 2019

Ile Igbimo Asofin seese ki won kowe wa wi tenu e si Gomina Eko ana Ogbeni Akinwunmi Ambode atawon merin miran niwaju awon igbimo ooluwadi.

Ipinnu yi waye latari abo awon Igbimo teekoto kan lati se iwadi oko boosi nla-nla ti Ogbeni Ambode ra.

Lara awon alamojugto ana toro kan ni ,Kazeem Adetunji, Olusegun Banje ,Ogbeni Akeem Asade ati Ogbeni Wale Oluwo.

Alaga Igbimo teekoto ohun, Ogbeni Mojeed so pe, won ko tele ilana to to lati ra awon oko boosi naa pelu afikun pe, owo Paris Club ni Gomoina ana lo kigbase lowo ile  bee owo rogunrogun ni won fi ra won ti won si fi ko won wole.

Won fi kun pe awon ti ranse pe awon alamojuto ana ohun sugbon won koti ogbon-in sebo awon ni.

Agbenuso Ile oloye Mudasiru Obasa so pe oro ohun koja oro anmuni tori pe iwa won yii koje awo kose rere, owa paa lase fakowe ile lati tun won pe.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background