IJOBA IPINLE EKO SUN OJO SISI ORI AFARA THIRD MAINLAND BRIDGE DI IPARI OSU KEJI TAWA YIN
Written by Christiana Akano on February 17, 2021
Ijoba Ipinle Eko Sun Ojo Sisi Ori Afara Third Mainland Bridge di ojo konkanlelogun osu keji Odun ti awa yi lati fun awon kongila ton sise nibe ni aye ati se ise daradara.
won ipinu naa waye lati fun awon to se atun laye lati ri daju pe ori afara naa komi papa julo ni gba ti awon oko ba wa gun orire.