IJOBA IPINLE EKO SOPE AWON O TU FENUKO LORI OFIN TO MAA MOJUTO IRINA AWON OLOKADA ATI ONI MARWA NILU EKO
Written by Christiana Akano on January 22, 2020
Ijoba ipinle Eko ti fidi okodoro oro mule pe awon tii fenuko lori oro awoon olokada ero atawon onikeke elese meta, Marwa lori opopona ti won ko gbodo gba nilu Eko.
Ninu atejade komisona Eto Iroyin ati Ogbon Atinuda, Ogbeni Gbenga Omotosho lo ti sope awon atejade oruko ojuupopo leseese to wa lori ero alatagba leyi to nsalaye awon ojuna tawon olokada atonimaruwa ko gbodo gba, won ni atejade naa kii sodo ijoba lo ti wa o, ayedeni si ni.
O sope tijoba ba to ari eto tiwon, araalu yoo mosi, kii sori ero alatagba tawon kan nko kiri le o ti riiatipe gbogbo eyikeyi igbese tijoba ba gbe, yoo je fun anfani idoola eni ati dukia araalu toripe isejoba Sanwo-Olu ko foro araalu sere.