IJOBA IPINLE EKO SELERI LATI PESE AYIKA TO RORUN FAWON OLOKOWO LATI GBERI

Written by on September 25, 2019

Ijoba Ipinle Eko ti setan lati pese ayika to rorun fawon onisowo lati gberisi nilu Eko.

Olori awon osise ijoba, Ogbeni Hakeem Muri-Okunola lo soro naa nibi apero to da lori sisowo niroun, eyi to waye lEko.

Akowe Agba Ajo to nrisoro awon osise, Ogbeni Ajibade Olusegun to sojufun olori awon osise ijoba nibi eto naa sope ijoba ti mu edinku ba ilana sisowo nilu Eko bayii nilu Eko.

Olori awon osise woye pe ijoba ipinle Eko gberufe apero naa ikale lati pese anfani fawon onisowo lati fararora pelawo olukowo o to ku, ati lati pese ise faraalu, fun idagbesoke eto oro aje.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background