IJOBA IPINLE EKO SE IFILO LE IGBIMO AWON ODO LEKA TEKO

Written by on October 29, 2019

Ijoba ipinle Eko ti se ifilole Igbimo awon odo Ile yii eka ti Eko..

Alamojuto fun  odo Ogbeni Segun Dawudu to ohun Nikeja ro awon ika asiwaju lati fi awon odo sokan ki won si ri i idaju pe, alafi joba laarin won nile yii.

       Ogbeni Dawodu gboriyin fun awon igbimo naa fun bi won ti se yanju awon jogbodiyan arin won lati bi odun meta seyin, leyi to fihan pe, awon odo ti setan lati ko ise isasiwaju.

        O  mu da won loju pe, Ileese naa yoo ma satileyin amojuto fun Igbimo naa pelu olikin pe, Ijoba ipinle Eko yoo maa seramo fawon odo pelu riro won lati ni imo ero leyi ti yoo ran wan lowo fun ilosiwaju won.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background