IJOBA IPINLE EKO FEE SOWOPO PELU AWON ALASE ILEESE ELEPO NNPC LORI AMOJUTO AWON OPA EPO TO GBA ILU EKO KOJA

Written by on January 22, 2020

Ijoba Ipinle Eko sope awon fee fowosowopo pelawon alase ileese elepo ileewa NNPC, lori ilana amojuto awon opa epo to gba ilu Eko koja .

Igbakeji gomina, Dr Obafemi Hamzat soro nalasiko to lo sabewo sibi ti opa epo na ti be ni Agbado/Oke-odo nipele Eko.

Dr Hamsat sope ijoba yoo tun sowopo pelawon olugbe adugbo na lori isele laabi awon odaran eda to ma nbe gooro epo.

Igbakeji gomina woye pe awon alase si wa lenu ise lori akosile nipa akoba tosele ijamba ina yi da sile lojuna ati seto bga mabinu fawon toro kan.

Alafia ijoba idagbasoke Agbado/Oke-Odo, ogbeni Adeoye Arogundade rawo ebe sawon alase lati tete wojuutu soro na nitori ewo ti o koba awon olugbe.

Lara awon olugbe naa salaye pe awon agbofinro to nso opa epo na ma npadi apopo mo awon odaran eda to nfo opa epo.

Oniroyin wa Olusegun Hastrup jabo wipe ninu iroyin lawon olugbe naa si wa dasukiyi, pelu eruku were were to sin nsuyo nibi isele naa.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background