IJOBA APAPO SOPE OFEGE NI FIDIO TO SIFIHAN ASOJU OMO NIGERIA TO WA NI BENNI REPUBLIC

Written by on October 14, 2019

IJOBA APAPO TO SOPE KO SOTO NINU FIDIO TAWON KOLORANSI EDA KAN LO GBE SORI ERO ALATAGBA PE WON KOLU OFUSI AWON ASOJU ILE NIGERIA TO WANI COTONU, LORILE EDE BENIN REPUBLIC.

ATEJADE LATAJO TO NRISISORO ILE-OKEERE, TI WON FI RIN AGBEWIRI EGBENIWU AJO NAA, FERDINAND NWONYE SOPE FIDIDO ATIYO NI WON GBE SORI ERO ALATAGBE, TO JE ISELE IKOLU TO WAYE LOFUSI AWON ASOJU ILE NIGERIA TO WANI DAKAR, LORILE EDE SENEGAL LOJO KERI KETA ODUN 2013.

ATEJADE NAA SOPE LOGUN LAWON ALASE FOWO SIKUN OFIN MU AWON TO WA MDI ISELE NAA, TO WON SI SOWON SEWON OSU TETO MEFA.

O WA RO ARAALU LATI MAA TETO SORO AWON ELEGAN TO NGBA AYEDENU IROYIN KIRI LATI FI KO EBERU SOKAN OMO NIGERIA.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background