GOMINA IPINLE EKO GBARADI LATI TUN OGOTA ILE IWE SE

Written by on October 29, 2019

           Ijoba Ipinle Eko loun ko ni feti layti seto ayika ti yoo faye gba awon odo lati samulo ebun won fun agbega Ipinle yii.

           Alamojuto fun awon odo ti idagbasoke amuludun, Ogbeni Segun Dawodu lo soro yii nibi iside eto IBILE to waye ni Onikan youth Centre ni Lagos Island.

           Ogbeni Dawodu ti akowe Egbe kan Arabinrin Yewande Falugba soju fun fihan pe, eto ohun to n lo kaakiri eka marun nipinle yii je ona lati ko awon odo ni ilana isasiwaju fun idagbasoke ile yii.

           O toka si ipe, Eto idanileko olodoodun ohun ti mu ki awon odo  maa ronu lona to to gege bi won ti se n fara ro awon asaaju lawujo leyi to bere lodun 2017 pelu ero igba lati pese ibugbe to roju fawon odo nipinle yii.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background