GBOGBO OMO LEYIN KRISTI BEERE AWE LENTI OLOGOJI OJO

Written by on February 17, 2021

Won ti ro ajo awon omo leyin Kristi lati maa se itore anu fun awon alaiini, gbigbadura fun Ile Nigeria ati gbigba awe pelu iberu Olorun bi Awe Lenti se bere jakejado gbogbo agbaye.

Alagba Ijo Saint Monica’s Catholic Church, Maza-maza ni Amuwa-Odofin local government ni Ilu Eko, Rev. Father Charles Unachukwu lo soro yin ninu Isin owuro ayajo Ojo Eru, Ashe Wednesday ni gbati o n fi ami Eru si ori awon olujosin.

Ayajo Ojo Eru ni ojo akoko ti Awe awon Kristeni bere ti awon omo leyin Jesu si maa gba Awe fun ogoji Ojo.

Rev. Father Unachukwu sope, odara ki awon omo Nigerian maa se itore anu, gbigbadura fun orileede won ati awe gbigba papa julo lasiko Awe Lenti ki orileede wa tunbo debi giga.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background