Politics

Page: 2

EGBE ASUU ATAWON MIRAN FAJURO SI SISUN AYEYE ASEKAGBA AWON AKEKO UNILAG SIWAJU
OKO AFAYAFA SEKUPA MOLEBI ELENI MARUN LORI OKADA NI KANO

Awon agbebon pa Eeyan meji, won ti ji alufa ijo Aguda gbe ni Kano,Benue .
Eni meji ti won furasi nipa Corona virus nilu Eko yege leyin ayewo ilera won, ko si aisan naa lara won.
Ileegbimo asoju beerefun alekun ipese owo fun amojuto corona virus .

Gomina Ipinle Eko, Ogbemi Babajide Sanwo=Olu ti fajuro sowon gogo ti won nta omi ifowo aoakokoro ati ibomu latari bi ero se nro ketiketi lo ra loja nitori aisan coronavirus to seleru nilu Eko latowo omo Italy to ko aisan naa wa silu Eko, ti won si fo sahamo sisamojuto ilera re leaye oto.

Abadofin to maa risi Ajo to nsakoso awon Ipinle to wani Guusu iwo Orun ileera to se bee moribi nibi ipinle kika eleekeji, nileegbimo asojusofin ileewa.

Ijoba Ipinle Eko sope, omo Ile China ti won mulo sileewosan Reddinghton nilu Ikeja latari pe won furasi pe o ni aisan Corona Virus , ni iwadi awon onisegun oyinbo pada fidere mule pe saka lara re da o.

Pelu bawon Kristen lagbaye se asajoyo ayajo Ojoru Eeru lori ode yin, won ti fun omo Nigeria papajulo awon kristen nimoran lati sunmo Olorun ninu adura , ise ore ati emi arojinle.

ILE EJO DA EWON ODUN MEJE FUN OLISA METUH ALUKORO PDP TELERI
IJOBA APAPO PE AWON AMUGBALEGBE OSINBAJO TI WON YO NISE PADA

IKOLU-KOGBA NIPINLLE BAYELSA NI GBATI SUPREME COURT NI APARO FUN DEBENI DAVID-LYDN NINU EGBA APC PEDUN OGBODO EGBE ASEFUN

Aya Gomina ti Ipinle Eko, Dokita Ibijoke Sanwo-Olu ti se ileri lati tesiwaju ati maa se iranlowo fun awon alaini ni Ipinle Eko papajulo, awon ti ijamba ina sele si ni Agbegbe Abule-Egba ni ibere Osu kinni Odun yi ti won si ko won lo si LASEMA IDO Camp, ni Igando.


Current track

Title

Artist

Background