Latest Updates

Page: 9

Ile Igbimo Asofin seese ki won kowe wa wi tenu e si Gomina Eko ana Ogbeni Akinwunmi Ambode atawon merin miran niwaju awon igbimo ooluwadi.

Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Babajide Sanwolu lawon yoo pari ise akanse omi to wa ni Adiyan lati le romi to ja gara mu fagooro omo Nigeria.

JONATHAN KAN SI BUHARI LASO-ROCK.
A KO KO AWON OMO NIGERIA WALE MO LATI SOUTH-AFRICA.

AGBARA ETO IDAGBASOKE NI GBOGBO AGBEGBE KO SE LEYIN ETO EKO TI A BA FUN AWON AKEKOO LATI IPELE ILEEWE ALAKOBERE.

Ipinle Ipinle Eko sope oun nsapa lati jeki gbogbo koto idominu to wa nilu Eko maa san ni geere.

Ijoba Ipinle Eko ti kesi awon olugbe lati lo forukosile feto adiyelofo ilera NHIS, tijoba ipinle Eko gbekale fun ipese ilera to jiire.

Ijoba Ipinle Eko tun ti tenumo ilakaka re lati jeki eto aabo gbogbo dee nilu Eko.

Ganduje, Lalong ,Tambuwal jawe olubori.
Awon asofin yoo gba Tirilionu meje owo eporobi pada.
Ki Buhari mase daa enu iloro pada –PDP

#Adelabare yio maa bosori afefe kete ti agogo merin-abo baa lu pelu #Iroyin, #Eto lorisirisi pelu #Ipolowooja ti ko gani lara. #E maa tetileko.

Ijoba Ipinle Eko beere iwadi nipa aisan to kolu awon akeko Ile-ewe Queens College
Omiyale se ose ni Ekiti, eyan kan lo ku


Current track

Title

Artist

Background