Latest Updates

Page: 6

Ijoba ipinle Eko ti fi ifokansi re han pe, eto akanse ile egbe Ilubinrin yoo pari lodun 2020.

Won ti kesi awon omo nigeria lati samulo awon ohun to rewa ninu bOlorun se da wa papo gege bi Orile –ede.

Omo Nigeria ni ojuse lati sowopo pelawon oloselu wa lojuna ati lulo mayederun faraalu.

Won ti kesi awon alase ileese panapana ijoba apapo atawon osise ajo to ndahun lasiko isele pajawiri lati tubo kojumose won lati dekun ijamba to nwaye lemolemo lawon oja wa lasiko.

Ijoba Ipinle Eko fi okan awon akeko ileewe ijoba ipinle Eko bale pe aabo gidi wa fun emi ati dukia won.

ILEEJO KAN LORILE EDE GBANA JU OMO NAIJIRIA SI EWON LORI ESU IBALOPO PELU OMODE
AWON OLOJA KAWO LORI LATARI OJA BALOGUN TO JONA

Ajo eso asobode ti sope atejade kan to gbana eburu bo sode, eyi to sopin ofin lati enuubode ile yio wa sopin lojo kokan lelogun osu kinni odun 2020, kiise otito botiimu o mo.

E YI GOMINA TI KO BA LE SANWO OSU TO KEREJULO FAWON OSISE KURO NIPO, EGBE OSISE NLC LO SO BE
AWON AFURA MEJI RA OMO MEJI NI EGBERUN LONA OGOJE NAIRA
ILAJI OWO AGBE YIO MAA FI RA IRINSE WON, MINISITA LO KEDE ORO

GOMINA ANA NIPINLE EKO AMBODE GBE ILEGBIMO ASOFIN LOSI ILEEJO.
OPIN IRIN AJO DE FUN ATIKU LORI IDIBO TOGBE BUHARI WOLE.
SECONDUS SOPE EGBE OSELU PDP TIFI IJASILE FUN OLORUN JA LEYIN IDAJO ILEEJO SUPREME COURT.

Ileegbimo asofin Ipinle Eko ti buwolu atunto akosile Eto Isuna Odun 2019 gegebi gomina Babajide Sanwo-Olu se nbeere fun.


Current track

Title

Artist

Background