Latest Updates

Page: 10

IGBIMO ALASE IJOBA FEC FOWOSI #3,46 FUN ISE AKANSE OJUUPOPO ATI ETO EKO
IGBAKEJI AARE OJOGBON YEMI OSINBAJO BERE IJA PELAWON ALALESI ORO

Ijoba Ipinle Eko ti setan lati pese ayika to rorun fawon onisowo lati gberisi nilu Eko.

Won ti ro awon obi ti omo won ni awon ipenija lati tete sawari ebun tawon omo bee ba ni ki won le ranwon lowo.

Ijoba Ipinle Eko ti fi agadagodo ti Ileese Ilera Okoo pa ninu Osu Kejo Odun lori esun aitele ofin bo tito ati bo tiye.

ASIKO TO LATI SE AGBEYEWO ILANA ETO AABO ILEEWA, ILEEGBIMO ASOFIN AGBA LO SO BEE
WON TI GBE DOKITA OYINBO LOSI TRIBUNAL LORI ESUN AIFOKANSI ITOJU ALABOYUN TO KU SI LAKATA

AWON ALAGA IJOBA IBILE ALIMOSHO TI GBARUKU TI ILANA ATI OFIN TO DAADO BO ETO AWON OMOBINRIN NIPA SISE ERANMO FUN IRUFE ILANA BEE FUN IDAGBASOKE AWON OMO BINRIN.

AJO ISOKAN AGBAYE TI RO GBOGBO ENIYAN LATI NI IMO NIPA FIFI AMI BANI SORO PATAKI JULO NITORI AWON AKANDA EDA TI ETI N YO LENU.

IJOBA IPINLE EKO TI MU DA AWON IGBIMO ONIDAJO LOJU PE, AWON YIO GBARUKO TIWON LATI MU AYIPA RERE BA ETO IDAJO GEGE BI ADAJO AGBA TUNTUN IPINLE YIN, ONIDAJO KAZEEM ALOGBA TI SE NI LOKAN.

Igbese ti ijoba apapo gbe lati salekun owo ori oja seese ko mu inira bawon to fe sowo nile Naijiira, o si le je kawon ileese kan kogba wole.

Gege bi ara akitiyan lati ridaju pe idasile olopa agbegbe rona lo ni Ipinle Eko, Aare ona kakanfo Ile yoruba, Oloye Gani Adams ti seleri lati sugba komisona ileese olopa ipinle Eko, Zubairu Muazu lori amojuto ipese aabo to peye nilu Eko.


Current track

Title

Artist

Background