Latest Updates

Ajo eso arinye ona ijoba apapo FRSC setan lati bere sii sowo sikun ofin mu awon oko to bi ti di eferemuti kuro lojupopo ile Nigeria.             Eyi wa lara igbiyanju iyo naa fodun 2021 lati dekun ijamba nileyi.             Aludan ago FRSC, Dr Boboye Oyeyemi ti wa paa lase fawon osise re lati bere […]

Lara awon iyawo oloopa to nsise ni ago oloopa Makinde ni Bakaki Oshodi ipinle Eko eyiti bareki naa jona, ti opo dukia bana sowo awon omo ganfe nigba fehonuhan Endsars ti seto iwode worowo lati kesijoba ki won ri ti won ro leyin isele laabi naa.             Awon to bale ise BondFM soro lara won […]

Ofiisi to nrisi itewon eto eko ninu ajo eleto eko in ipinle Eko ti bere ayewo asawon ileewe ijoba ati taladani lati bere depele girama ki won le de ileewe to mu ilera akeko nibabara mo. Ofisi to saaju funwon ileewe ijoba ati taladani nipinle Eko lati fokanbae pelu ofisi lori adiresi ero alagbada, ko […]

https://fb.watch/3C2U0KQiY2/

https://fb.watch/3zrb8YsVyW/

Ajo ton jafato omo eyan labe ijoba apapo ti pinnu lati fiya toho je awon ton deye sawon obinrin atawon tiwon nafiya jewon. Nigbati won soro nibi ijoko itokumkun won nipinle Eko, Okan lara awon olukopa igbimo naa Ojogbo AbdulRahom Yusuf, seloye pe ajo awon ti gbe igbese akeri lati ki awon ti won fipa […]

Aare orileede yii Aare Mohamodun Buhari ti so di mimo pe iranlowo orileede China fun Ile wa po jojo. Aare Buhari soro yi ninu iwe apilero ti won buwolu eyi won ti sowo si enikeni won Aare orileede China Aare Xi Jinping lati senu ibesepo aledote Odun towa laarin orileede omo Nigeria ati awon omo […]

Awon #Eto, #Iroyin ati #Ipolowooja ni Ede Yoruba n tee siwaju titi di agogo mejila-abo osan #Bondfm929. E maa bawabo

Egbe awako oko afayafa nile Nigeria ti rawo ebe si ijoba apapo lati pase fawon agba isese to nsise ojuko marose Oshodi-Apapa ati Tincan si Mile 2 ki idamu to won nkoba awon awako oko afayafa dinku jojo.

Ijoba ipinle Eko ti rawo ebe sawon ero ti nlo ojuupopo lati se suru fun ijoba toripe won o feki ojo sakoba fawon ise akanse lo jeki won dawole opolopo ise akanse papo lasiko kan naa.


Current track

Title

Artist

Background