Featured

Lara awon iyawo oloopa to nsise ni ago oloopa Makinde ni Bakaki Oshodi ipinle Eko eyiti bareki naa jona, ti opo dukia bana sowo awon omo ganfe nigba fehonuhan Endsars ti seto iwode worowo lati kesijoba ki won ri ti won ro leyin isele laabi naa.             Awon to bale ise BondFM soro lara won […]

Won ti ro ajo awon omo leyin Kristi lati maa se itore anu fun awon alaiini, gbigbadura fun Ile Nigeria ati gbigba awe pelu iberu Olorun bi Awe Lenti se bere jakejado gbogbo agbaye. Alagba Ijo Saint Monica’s Catholic Church, Maza-maza ni Amuwa-Odofin local government ni Ilu Eko, Rev. Father Charles Unachukwu lo soro yin […]

https://fb.watch/3zrb8YsVyW/

Ajo ton jafato omo eyan labe ijoba apapo ti pinnu lati fiya toho je awon ton deye sawon obinrin atawon tiwon nafiya jewon. Nigbati won soro nibi ijoko itokumkun won nipinle Eko, Okan lara awon olukopa igbimo naa Ojogbo AbdulRahom Yusuf, seloye pe ajo awon ti gbe igbese akeri lati ki awon ti won fipa […]

Awon #Eto, #Iroyin ati #Ipolowooja ni Ede Yoruba n tee siwaju titi di agogo mejila-abo osan #Bondfm929. E maa bawabo

Egbe awako oko afayafa nile Nigeria ti rawo ebe si ijoba apapo lati pase fawon agba isese to nsise ojuko marose Oshodi-Apapa ati Tincan si Mile 2 ki idamu to won nkoba awon awako oko afayafa dinku jojo.

Ijoba ipinle Eko ti rawo ebe sawon ero ti nlo ojuupopo lati se suru fun ijoba toripe won o feki ojo sakoba fawon ise akanse lo jeki won dawole opolopo ise akanse papo lasiko kan naa.

EGBE ASUU ATAWON MIRAN FAJURO SI SISUN AYEYE ASEKAGBA AWON AKEKO UNILAG SIWAJU
OKO AFAYAFA SEKUPA MOLEBI ELENI MARUN LORI OKADA NI KANO

Awon agbebon pa Eeyan meji, won ti ji alufa ijo Aguda gbe ni Kano,Benue .
Eni meji ti won furasi nipa Corona virus nilu Eko yege leyin ayewo ilera won, ko si aisan naa lara won.
Ileegbimo asoju beerefun alekun ipese owo fun amojuto corona virus .


Current track

Title

Artist

Background