Business

Page: 3

Ile Igbimo Asofin seese ki won kowe wa wi tenu e si Gomina Eko ana Ogbeni Akinwunmi Ambode atawon merin miran niwaju awon igbimo ooluwadi.

Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Babajide Sanwolu lawon yoo pari ise akanse omi to wa ni Adiyan lati le romi to ja gara mu fagooro omo Nigeria.

AGBARA ETO IDAGBASOKE NI GBOGBO AGBEGBE KO SE LEYIN ETO EKO TI A BA FUN AWON AKEKOO LATI IPELE ILEEWE ALAKOBERE.

Ijoba Ipinle Eko beere iwadi nipa aisan to kolu awon akeko Ile-ewe Queens College
Omiyale se ose ni Ekiti, eyan kan lo ku

IGBIMO ALASE IJOBA FEC FOWOSI #3,46 FUN ISE AKANSE OJUUPOPO ATI ETO EKO
IGBAKEJI AARE OJOGBON YEMI OSINBAJO BERE IJA PELAWON ALALESI ORO

Ijoba Ipinle Eko ti setan lati pese ayika to rorun fawon onisowo lati gberisi nilu Eko.

Igbese ti ijoba apapo gbe lati salekun owo ori oja seese ko mu inira bawon to fe sowo nile Naijiira, o si le je kawon ileese kan kogba wole.

Ijoba apapo ni won ti gba niyanju ona abayo bi ayika papako ofurufu yio ti se fini lokanbale ti yio siri idagbasoke.

Ileegbimo Asofin Ipinle Eko tigbe Igbimo oniwadi kale latise iwadi lori oko boginni ogorun mejo ati ogun ti isakoso Gomina ana Ogbeni Akinwunmi Ambode ra lasiko isejobare.

MEJILA NINU AWON OLOYE ATI AWON ALAGA TO LE LOGORUN EGBE AWAKO EKO SO PE GBAGBA LAWON WA LEYIN AKAPO EGBE NAA ALHAJI MUSILU AKINSANYA MC-OLUOMO LATI DI ALAGA AWON NIPINLE EKO.


Current track

Title

Artist

Background