Business

Ijoba Ipinle Eko Sun Ojo Sisi Ori Afara Third Mainland Bridge di ojo konkanlelogun osu keji Odun ti awa yi lati fun awon kongila ton sise nibe ni aye ati se ise daradara. won ipinu naa waye lati fun awon to se atun laye lati ri daju pe ori afara naa komi papa julo ni […]

https://fb.watch/3C2U0KQiY2/

https://fb.watch/3zrb8YsVyW/

Aare orileede yii Aare Mohamodun Buhari ti so di mimo pe iranlowo orileede China fun Ile wa po jojo. Aare Buhari soro yi ninu iwe apilero ti won buwolu eyi won ti sowo si enikeni won Aare orileede China Aare Xi Jinping lati senu ibesepo aledote Odun towa laarin orileede omo Nigeria ati awon omo […]

ILE EJO DA EWON ODUN MEJE FUN OLISA METUH ALUKORO PDP TELERI
IJOBA APAPO PE AWON AMUGBALEGBE OSINBAJO TI WON YO NISE PADA

Aya Gomina ti Ipinle Eko, Dokita Ibijoke Sanwo-Olu ti se ileri lati tesiwaju ati maa se iranlowo fun awon alaini ni Ipinle Eko papajulo, awon ti ijamba ina sele si ni Agbegbe Abule-Egba ni ibere Osu kinni Odun yi ti won si ko won lo si LASEMA IDO Camp, ni Igando.

Ijoba ipinle Eko ti fidi okodoro oro mule pe awon tii fenuko lori oro awoon olokada ero atawon onikeke elese meta, Marwa lori opopona ti won ko gbodo gba nilu Eko.

OWO ELE ORI EPO TIJOBA APAPO NFUN AWON OLOJA EPO SEESE KO TUN LO SOKE LATARI ALEKUN TI WON NBEERE FUN

AWON AGBAAGBA ILE YORUBA ATI AWON AGBEJORO AGBA BU ENU ATE LU MALAMI LORI OHUN TI O SO NIPA AMOTEKUN

ISEJOBA TOWA LODE NIPINLE EKO YIO TUBO TESIWAJU IGBESE IMOTOTO AYIKA NIPASE AJOSEPO TO DANMORAN PELAWON, PAAJULO AWON OBINRIN ATAWON ONTAJA.


Current track

Title

Artist

Background