AYA GOMINA KESI ARAALU LATI FURA

Written by on November 12, 2019

Aya gomina Ipinle Eko, Arabirin Ibijoke Sanwo-Olu ti so si gbogbo eniyan leti pe, oun ko ni nkankan se pelu eto egbe ti ki i se tijoba kan South-Westtuie Health Trust lati maa ko awon to ku die kaato fun kuro loju popo.

Arabirin Sanwo-Olu soro yin ninu atejade kan ti won fi soro sawon oniroyin latodo amugbalegbe re lori oro ilu loofisi aya gomina-Arabirin Olubukola Nwonah.

O sapeju oro ohun gege bi iro tori pe, iru eto bee ko waye larin won.

Aya gomina salaye pe, looto lawon iko to n sakoso  egbe ti ki i se tijoba nibi kan so nu fun niran lowo sugbon oun ko bawon seru adehun a n ko isoro awon eniyan ohun loju popo.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background