ALEKUN OWO INA OMNAMONA KO GBODO WAYE-ILEEGBIMO ASOJUSOFIN LOSOBE

Written by on January 15, 2020

ILEEGBIMO ASOJUSOFIN TI PAA LASE PE KO GBODO WAYE O, IYEN BI AJO TO NRISI IDIYELE OWO INA MONAMONA SE NGBORO LATI SALEKUN IYE OWO INA TARAALU NLO.

ALAGA IGBIMO ALABESEKELE TI NRISORO INA MONAMONA, OGBENI MOGAJI DAU LO SORO NAA NINU IFOROWERO PELU AWON OSISE AJO TO NRISI IDIYELE OUN INA MONAMONA.

OGBENI DAU TENUMO PE IGBESE NAA KO BOJUMU PELU ALESO TAWON ASOJU ILEESE IDIYELE OUN INA NAA O SO WIPE IGBESE NAA WAYE PELU OYE MINISITS ETO NAWO, TO GBA ASE LATI LEESE AARE.

EWE, ALAGA AJO TO NSIRI IDIYELE OWO NA, OJOGBON JAMES MOMOH TI SAAJU SI LOSE TO KOJA PE KISE LESEKESE LEKUNWO NAA NLERA.

OJOGBON MOMOH SALAYE PE AJO NSISE TAKUN LATI PIN ERO AKONA, PREPARED METER KO LE  KARI  WON ONIBARA PELAFIKUN PE OFIN KAN NBO LATI KAN NIPA LATI PE ERO TO NKAYE INA- PREPARED METER KI KONI GBOGBO AWON ONIBARA WON.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background