AKANSE ILE EGBE

Written by on November 12, 2019

Ijoba ipinle Eko ti fi ifokansi re han pe, eto akanse ile egbe Ilubinrin yoo pari lodun 2020.

Alamojuto fun oro Ile gbee nipinle yii, Ogbeni Moruf Akinderu Fatai so eleyi di mimo nigba ti o kan si ibi Ise Akanse ohun.

Ogbeni Akinderu-Fatai so pe, eka eyi to je ibugbe ise naa yoo pari lodun 2020 nigba ti eka igba-fe re maa pari lodun 2021.

O gbosuba fun agbasese to wa nibi eto naa lati je ki o wa si imuse.

Alamojuto ohun salaye pe, ojuko akoko ile gbe ilubinrin ohun yoo pese ilegbe to le logorun ti laye daadaa jakejado alaale, ile-nla nla maraarun.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background