AJO TON JAFATO OMO EYAN LABE IJOBA APAPO TI PINNU LATI FIYA TOHO JE AWON TON DEYE SAWON OBINRIN ATAWON TIWON NAFIYA JEWON
Written by Christiana Akano on February 9, 2021
Ajo ton jafato omo eyan labe ijoba apapo ti pinnu lati fiya toho je awon ton deye sawon obinrin atawon tiwon nafiya jewon.
Nigbati won soro nibi ijoko itokumkun won nipinle Eko, Okan lara awon olukopa igbimo naa Ojogbo AbdulRahom Yusuf, seloye pe ajo awon ti gbe igbese akeri lati ki awon ti won fipa nolo ni tipa laya, lati soro sita atawon obinrin toku tiwa feto won duu, nigbati won pe awon elesin lati ji giri si ojuse won ki won nipe won fopinsi fiyajeni laito lawujo wa.
Won wa ro awon ti won n fara kese ifi jeni oun lati fokan eokan naa soro soke lasiko ti won beh kolu awonpaapa nigbati eri to daju bawa lati figege awon ti won feto won dun won.
Asoju ajo Ilera awon obinrin, abileko Bose Iro-nsi woye pe pupo ninu esin ifipabanilopo ati ideye si sobirin maa nsaba sele ni igberiko wa, o ni ojuse gbogbo pe ajo awon ti gbe igbese