AJO TO NDEKUN IWA AJEBANU EFCC SOPE GBOGBO AWON TO KOWO ILU SAPO ARAAWON TI WA LOKE OKUN NI WON MAA WO PADA WALE LATI WA KOJU OFIN

Written by on January 22, 2020

Adele Ogaagba ajo to ndekun iwa ajebanu EFCC, Ogbeni Ibrahim Magu sope ko dinsi mejidinlogun lara awon ti won kowo ilu yi sapo araawon ti won yoo fi tipa tikuuku wo lati wa jeje laipe.

Ogbeni Magu to kede oro naa nilu Ilorin sope ibeere Aare Muhammadu Buhari nilu London wipe ki won fawon to kowo ilu sapo soko pada sorile ede Nigeria, je gbese akoko ajo EFCC lati segun iwa ajabanu lona kona.

O sope pupo lara won to wa loke okun ni won a bere sii wo pada sile Nigeria bayii toripe aaya ajo EFCC ti be sile, bayii, o be sise ni lakotun.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background