AARE MUHAMADU BUHARI KILO FAWON OLOOPA LORI SISI AGBARA LO LORI AWON ODO LOJUNA ATI FOPIN SI IWA JIBITI ERO AYELUJARA

Written by on October 29, 2019

Aare Muhamadu Buhari ti kilo fawon olopaa lati sora se nipa lilo ipa ati agbara lona aito fawon odo latari oro aigbogun ti iwa madaru ayelujara.

         Aare Buhari to soro yii nibi Iside Ipade  olojo meta fawon oga lenu ise olopaa leko so pe, Ose pataki lati fidi ajosepo to dan moran mule laarin won ati awon araalu ki ise won le rorun ni sise.

        O so pe, ise takuntakun lawon olopaa n se kaakiri ile yii ati ile adulawo lapapo. Are ti igbakeji re, Ogbeni Yemi Osinbajo soju fun ro awon olopaa lati ri i daju pe, owa ijiya to eyikeyi olopaa to ba tabe apere.

       Ninu oro tire, Gomina Babajide Sanwoolu ti igbakeji re, Omowe Obafemi Hamzat soju fun sope, oun yoo satileyin fun awon olopaa lenu ise won.

       Alakoso fun oro awon olopaa, Ogbeni Mohammed Danyadi so pe, ipade naa waye lakoko to ye ti Are Buhari ni in lokan lati tun ise olopaa to daadaa nipa ifilole awon eto fawon olopaa ki won le de ipele to ga.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background